إعدادات العرض
Àwọn orúkọ ati awọn ìdájọ́
Àwọn orúkọ ati awọn ìdájọ́
1- Wọn mọ Isilaamu pa lori nkan márùn-ún
2- “Ọlọhun, má ṣe sọ saare mi di òrìṣà
8- Ẹni ti o ba da adadaalẹ kalẹ sinu alamọri wa yii ninu nnkan ti ko si nibẹ, wọn maa da a pada ni
14- Wọn mọ Isilaamu pa lori nkan márùn-ún
21- Ẹ yára si awọn iṣẹ daadaa siwaju ki awọn fitina kan ti yio da bii oru ti o ṣokunkun gan o to de,
27- ”O ti jere ti o ba sọ ododo”
31- ko fi ọjọ kan sọ pé: Irẹ Oluwa mi, fori awọn àṣìṣe mi jin mi ni ọjọ ẹsan
36- O gba Isilaamu lori nnkan ti o ṣáájú ninu daadaa”
41- emi ni Dimaam ọmọ Tha’labah, láti ìdílé Banuu Sahd ọmọ Bakr
42- Awọn Juu ni awọn ti a binu si, ti awọn Nasara jẹ awọn ẹni anu
43- Sọ pe: LAA ILAAHA ILLALLOOH, maa fi jẹ́rìí fun ọ ni Ọjọ́ Àjíǹde
45- Ẹni ti o ba kọ oju ija si wa pẹlu ohun ìjà, ko kii ṣe ara wa
